Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
score
float32
1.04
1.25
Ganda
stringlengths
10
500
Yoruba
stringlengths
9
495
1.249007
era n'eggulu mirimu gwa mukono gwo.
Iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni àwọn ọ̀run.
1.248579
Kyandibadde kirungi singa omuntu oyo teyazaalirwa ddala."
Ìbá sàn fún ọkùnrin náà bí a kò bá bí i. "
1.248075
Noolwekyo kikkirizibwa okukola ekirungi ku Ssabbiiti."
Nítorí náà ó yẹ láti ṣe rere ní ọjọ́ ìsinmi."
1.247569
Kale, lwaki mwekulumbaliza ku kibiina ky'abantu ba Mukama?"
Ẽṣe ti iwọ gbe ara loke awọn enia Oluwa?"
1.247406
so n'emyaka gyo tegirikoma."
àti pé ọdún rẹ kì yóò ní òpin."
1.246602
30 Tewali kintu na kimu kye nnyinza kukola ku bwange.
30 Emi ko le ṣe ohunkohun fun ara mi.
1.246323
Okutuusa lw'anaatulaga ekisa.+
títí yóò fi ṣàánú fún wa.
1.244425
kyokka bali wala n'amateeka go.
ṣùgbọ́n wọ́n jìnnà sí òfin rẹ.
1.244025
Kale ayinza atya okugamba nti, 'Nava mu ggulu?' "
Ki o si bi o ti le ti o sọ: 'Nitori emi sọkalẹ lati ọrun wá?'"
1.243473
Kwe kugamba Labbaani nti, "Onkoze ki kino?
Ó sì wí fún Labani pé, "Èwo ni ìwọ ṣe sí mi yìí?
1.243401
ne wakati w'ezzadde lyo n'ezzadde ly'omukazi;
àti sí àárín irú-ọmọ rẹ àti irú-ọmọ obìnrin náà;
1.243316
era Mukama wange anneerabidde."
Olúwa ti gbàgbé è mi."
1.243154
Tukwebaza, kubanga Erinnya lyo liri kumpi.
a yìn ọ́, nítorí orúkọ rẹ súnmọ́ tòsí;
1.243101
Tajja kuyingira mu kibuga kino,"
òun kì yóò wọ inú ìlú yìí,"
1.242313
Ebyo, mbibabuulidde muleme okusittazibwanga.
"Mo sọ gbogbo nǹkan yìí fun yín kí igbagbọ yín má baà yẹ̀.
1.241875
Nammwe abavubuka, mbawandiikidde
Èmi ń kọ̀wé sí yín, ẹ̀yin ọ̀dọ́mọkùnrin,
1.241773
Anga omuntu aligiraki kuchungura oburorabwe? 27Manyasi Omwana w'Omuntu alija n'abamalaikabe omu kitinwa nk'ekya Ishe, arongore buli omoi aha rw'ebyo yakozire.
27 Nitori Ọmọ-enia yio wá ninu ogo Baba rẹ̀ pẹlu awọn angẹli rẹ̀; nigbana ni yio san a fun olukuluku gẹgẹ bi iṣẹ rẹ̀.
1.24176
muwulirize Isirayiri kitammwe.
Ẹ fetí sí Israẹli baba yín.
1.240438
14Ak ye kingo kagonyoor Jeso moitap sigiryet, kolaany; ko uu ye ki kisir keele:
14 Nígbà tí Jesu sì rí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kan, ó gùn ún; gẹ́gẹ́ bí a ti kọ̀wé pé,
1.240383
Kale ayinza atya okugamba nti, 'Nava mu ggulu?' "
Báwo ni ó ṣe wí pé, 'Èmi ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá'?"
1.239451
Kyokka mmwe si bwe mwayigirizibwa ku bya Kristo.
Ṣugbọn a kò kọ́ ẹ̀yin bẹ́ẹ̀ nípa Kristi.
1.239312
n'erinnya lya Isirayiri lireme okujjukirwanga emirembe gyonna!"
kí orúkọ Israẹli ma bá a sí ní ìrántí mọ́."
1.238231
Naye mutyenga oyo yekka, ayinza okuzikiriza byombi omwoyo n'omubiri mu ggeyeena.
Ẹni tí ó yẹ kí ẹ bẹ̀rù ni Ọlọrun tí ó lè pa ẹ̀mí ati ara run ní ọ̀run àpáàdì.
1.237779
amu po iman ak ko po imanda kirwoogutikyik; amu kagorwookyi chepkugoniot ne oo, ne ki imurwon ng'wony eng' soksennyi, ak kagoyaakta mugetuut ne po korotiigap otwogikyik eng' eutap kwonyooto." 3
Nitori otitọ ati ododo ni idajọ rẹ̀: nitori o ti ṣe idajọ àgbere nla nì, ti o fi àgbere rẹ̀ ba ilẹ aiye jẹ, o si ti gbẹsan ẹ̀jẹ awọn iranṣẹ rẹ̀ lọwọ rẹ̀.
1.237361
Awo Ibulaamu n'amuwa ekitundu eky'ekkumi ekya buli kimu.
Abramu sì fún un ní ìdámẹ́wàá ohun gbogbo.
1.236485
7Herode amuraganisa nanahira kumuha kyona kyona ekyo arashaba.
tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi fi ìbúra ṣe ìlérí láti fún un ní ohunkohun tí ó bá bèèrè.
1.236485
era ndiwonya ennyumba ya Yusufu,
èmi o sì gba ilé Josẹfu là,
1.235751
eyabakolera ebintu ebikulu bwe bityo mu Misiri,
ẹni tí ó ti ṣe ohun ńlá ní Ejibiti,
1.234752
era twandifaananye nga Ggomola."
a bá sì ti sọ wá dàbí Gomorra."
1.233146
Fesuto n'addamu nti, "Enkya onoomuwulira."
"Fẹstu dáhùn ó ní, "Ẹ óo gbọ́ ọ̀rọ̀ lẹ́nu rẹ̀ lọ́la.
1.231835
era n'eggulu mirimu gwa mukono gwo.
Awọn ọrun si jẹ iṣẹ ọwọ rẹ.
1.231657
era n'eggulu mirimu gwa mukono gwo.
àwọn ọ̀run sì jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ ara rẹ.
1.231371
Bwanyima yaataaha omuka owaabo, 20kandi ekimbuuro ky'abantu nabwo kyateerana, n'ahabw'ekyo Yesu n'abatendekwa be tibaabaasa na kurya.
Lẹ́yìn náà, Jesu wọ inú ilé lọ, àwọn eniyan tún pé jọ tóbẹ́ẹ̀ tí òun ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ kò fi lè jẹun.
1.231105
kitya nga nze nalaba ekisa mu maaso go, nze n'abantu bo? si kyekiriva
Nítorí pé, báwo ni àwọn eniyan yóo ṣe mọ̀ pé, inú rẹ dùn sí èmi ati àwọn eniyan rẹ?
1.231047
6 Kitalo: kubanga, (bwe kiba bwe kityo), Katonda alisalira atya ensi omusango?
6 Ki a má ri: bi bẹ̃ni, Ọlọrun yio ha ṣe le dajọ araiye?
1.230675
Katonda akyakola ebyamagero.
Ọlọ́run sì ńṣe ìyanu.
1.230621
n'okakanyaza omutima gwaffe, ne tutakutya?
Ṣe ti iwọ fi le ọkàn wa le, nitorina ki awa má bẹru rẹ?
1.230226
Kyokka mmwe si bwe mwayigirizibwa ku bya Kristo.
Ṣùgbọ́n a kò fi Kristi kọ́ yín bẹ́ẹ̀.
1.230186
Ab'eggwanga lyammwe ne bakabona abakulu be bakundeetedde: okoze ki?
Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè rẹ, àti àwọn olórí àlùfáà ni ó fà ọ́ lé èmi lọ́wọ́: kín ní ìwọ ṣe?"
1.229575
Yerusaalemi ajja kufuuka ntuumu ya mafunfugu,
Jerusalẹmu yóò sì di ebè
1.22919
Totya ggwe Yakobo,[a] omuweereza wange,
Má ṣe bẹ̀rù, ìwọ Jakọbu, ìránṣẹ́ mi,
1.229133
"Nze, Nze mwene, nze Mukama; okuggyako nze tewali Mulokozi."
"Èmi ni OLUWA,kò sí olùgbàlà kan, yàtọ̀ sí mi.
1.229001
Ataliwuliriza nnabbi oyo abantu balimuzikiririza ddala.'
Yóò sì ṣe, olúkúlùkù ọkàn ti kò bá gbọ́ ti wòlíì náà, òun ni a ó parun pátápátá kúrò nínú àwọn ènìyàn rẹ̀.'
1.228857
Mukama n'ayita omusajja nti, "Oli luuyi wa?"
Ṣùgbọ́n OLúWA Ọlọ́run ké pe ọkùnrin náà pé, "Níbo ni ìwọ wà?"
1.228003
Ataliwuliriza nnabbi oyo abantu balimuzikiririza ddala.'
Ẹnikẹ́ni tí kò bá gbọ́ràn sí wolii náà lẹ́nu, píparun ni a óo pa á run patapata láàrin àwọn eniyan Ọlọrun.
1.22797
"Musiriikirire mutegeere nga nze Katonda.
"Ẹ dúró jẹ́ẹ́, kí ẹ sì mọ̀ pé èmi ni Ọlọrun.
1.227535
Anaawa abantu be ennyama?"
ó ha le pèsè ẹran fún àwọn ènìyàn rẹ̀"
1.227341
17 Isiraeri n'alyoka ayimba oluyimba luno:
17 Nígbà náà ni Israẹli kọ orin yìí pé:
1.226787
11 Ebigambo ebyo ne bifaanana mu maaso gaabwe nga bya busirusiru; ne batakkiriza.
11 Ọ̀rọ wọnyi si dabi isọkusọ loju wọn, nwọn kò si gbà wọn gbọ́.
1.226782
olimalayo ennaku musanvu ndyoke njije gy'oli nkutegeeze by'oba okola.
Fún ọjọ meje, ki iwọ ki o duro, titi emi o de si o, ki o si fi si o ohun ti o yẹ ki o ṣe. "
1.226757
Naye omuti ogw'okumanya ekirungi n'ekibi togulyangako. - Lub.
Ní ti igi ìmọ̀ rere àti búburú, ìwọ kò gbọ́dọ̀ jẹ nínú rẹ̀. - Jẹ́n.
1.226123
22 Era ejjinja lino lye nsimbye okuba empagi liriba nnyumba ya Katonda, era n'ebyo byonna by'ompa ndikuwaako ekimu eky'ekkumi."
Òkúta tí mo sì gbé nàró bí ọ̀wọ̀n yìí yóo di ilé Ọlọrun, n óo sì fún ìwọ Ọlọrun ní ìdámẹ́wàá ohun gbogbo tí o bá fún mi.
1.226015
so tetulina busika mu mutabani wa Yese: mudde mu weema
bẹ́ẹ̀ ni àwa kò ni ìní nínú ọmọ Jese!
1.225547
42Tebajjukira buyinza bwe;
42 Wọ́n kò rántí agbára rẹ̀:
1.225248
Ndibaawula mu Yakobo,
Èmi yóò tú wọn ká ní Jakọbu,
1.224649
"Kino ekiri mu mukono gwange ogwa ddyo si bulimba?"
"Ǹjẹ́ nǹkan tí ó wà lọ́wọ́ ọ̀tún mi yìí irọ́ kọ́?"
1.224139
kubanga twesiga erinnya lye ettukuvu.
nítorí pé, àwa gbẹ́kẹ̀lé orúkọ rẹ mímọ́.
1.223725
Labbaani n'ayogera nti Entuumu eno ye mujulirwa eri nze naawe leero.
Labani wí pé, "Òkítì yìí ni ohun ẹ̀rí láàrin èmi pẹlu rẹ lónìí.
1.223588
twandifuuse nga Sodomu,
àwa ìbá ti dàbí Sodomu,
1.223267
Yingira osanyukire wamu ne mukama wo.'
Wọ inu didùn ti oluwa rẹ. '
1.222731
Muwala wange atawaanyizibwa dayimooni."+ 23 Naye n'atamuddamu kigambo kyonna.
Ẹ̀mí èṣù gbé ọmọbìnrin mi dè burúkú-burúkú." 23 Ṣùgbọ́n kò sọ ọ̀rọ̀ kan ní ìdáhùn fún un.
1.222334
21 "Jjukira ebintu bino, ggwe Yakobo;
21 "Rántí àwọn nǹkan wọ̀nyí, ìwọ Jakọbu
1.222277
Naye ffe tuli bayigirizwa ba Musa.
Ṣugbọn ọmọ-ẹhin Mose ni awa.
1.22194
Bangi bino balibiraba ne batandika okutya Mukama
Ọ̀pọ̀ yóo rí i, ẹ̀rù óo bà wọ́n,wọn óo sì gbẹ́kẹ̀lé OLUWA.
1.22188
maaso ge: Mukama atusalire omusango nze naawe.
Kí Olúwa kí ó ṣe ìdájọ́ láàrín tèmi tìrẹ."
1.221789
Haakiri mutiine Ogwo orikubaasa kucwekyereza byombi, amagara g'omutima n'omubiri okuzimu omu muriro.
Ẹni tí ó yẹ kí ẹ bẹ̀rù ni Ọlọrun tí ó lè pa ẹ̀mí ati ara run ní ọ̀run àpáàdì.
1.221748
Naye mu kifo kyokubawa ensonga, Yesu yabaddamu nti, "Sikugambye nti Bw'onokkiriza, onoolaba ekitiibwa kya Katonda?"
Jesu wí fún un pé, "Ṣebí mo ti sọ fún ọ pé bí o bá gbàgbọ́ ìwọ yóo rí ògo Ọlọrun."
1.221488
"Nayita Omwana wange okuva mu Misiri."
→ "Lati Egipti ni Mo ti pe ọmọ mi."
1.221249
21 Ibulayimu jjajjaffe teyaweebwa butuukirivu lwa bikolwa, kubanga yawaayo Isaaka omwana we ku kyoto?
Nípa iṣẹ́ kọ́ ni Abrahamu baba wa fi gba ìdáláre, nígbà tí ó fa Isaaki ọmọ rẹ̀ lọ sí orí pẹpẹ ìrúbọ?
1.221131
Kwatagana Naffe ku Twiter ne Instagram!
Darapọ̀ Mọ́ Wa lóri Twitter àti Instagram!
1.221038
23 Ani mu mmwe aliwulira kino?
23Ta ni nínú yín tí yóò tẹ́tí sí èyí
1.221017
Abantu baingi ku baakihuriire, baaruga omu birorero, baamukurata nibagyendesa ebigyere.
Ati nigbati awọn enia ti gbọ ti o, ẹsẹ ni wọn fi tọ̀ ọ lẹhin lati awọn ilu na.
1.220831
Ati: 3Mukama, reeba, baitsire abarangi baawe, baasheenya amatambiro gaawe, mbwenu niinye ntsigaireho nyenka, kandi naanye nibenda kuunyita.
"Oluwa, wọ́n ti pa àwọn wolii rẹ, wọ́n ti wó pẹpẹ ìrúbọ rẹ, èmi nìkan ṣoṣo ni ó kù, wọ́n sì ń wá mi láti pa.
1.220403
14Ak ye kingo kagonyoor Jeso moitap sigiryet, kolaany; ko uu ye ki kisir keele:
Jesu rí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kan, ó bá gùn un, gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé,
1.219723
Kwonka nyowe nimbagambira nti: otarirahira n'akakye, nobu ryakuba eiguru ahabw'okuba n'ekitebe kya Ruhanga eky'obugabe" (Mat.
Ṣugbọn èmi wá ń sọ fun yín pé, ẹ má ṣe búra rárá; ìbáà ṣe pé kí ẹ fi ọ̀run búra, nítorí ìtẹ́ Ọlọrun ni;
1.219488
19 Kubanga amagezi ag'omu nsi muno bwe busirusiru eri Katonda.
19 Nitori ọgbọ́n aiye yi wèrè ni lọdọ Ọlọrun.
1.219367
Ramya Ruhanga! 10Ayongyera angira ati: Yata enaama y'ebigambo by'oburangi ebiri omu kitabo eki, ahabw'okuba obunaku bw'ebyo bintu byona kuhikiirira buri haihi.
Ó tún sọ fún mi pé, "Má ṣe fi èdìdì di àwọn ọ̀rọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ ìwé yìí nítorí àkókò tí wọn yóo ṣẹ súnmọ́ tòsí.
1.219316
nti Oli ku lwaffe, oba oli ku lwa balabe baffe? 14 N'ayogera nti Nedda;
O si wi fun u pe, "O wa ti o ọkan ninu awọn tiwa, tabi ọkan ninu awọn ọtá wa?"
1.219108
ndizikiririza ddala ebibuga byabwe.
èmi yóò sì pa ìlú ńlá rẹ̀ run.
1.219041
Bakubuuza gwe (Nabbi Muhammad) ebikwata ku lunaku lw'enkomerero, nti lulibaawo ddi.
{wọn o maa bi ọ nipa Asiko (Ọjọ ikẹyin) igba wo ni yoo de?
1.21901
ggwe Isirayiri sirikwerabira.
ìwọ Israẹli, Èmi kì yóò gbàgbé rẹ.
1.218813
era tewaliba n'omu aliwulira eddoboozi lye mu nguudo.
ẹnikẹ́ni kì yóò gbọ́ ohùn rẹ ní ìgboro.
1.218753
era ndimulaga obulokozi bwange."
èmi yóò sì fi ìgbàlà mi hàn án."
1.21861
Yesu akabatebia eria kabere, Omorembe obe asemore: buna Tata antomete, naboigo nabatomire inwe.
Nítorí náà, Jésù sì tún wí fún wọn pé, "Àlàáfíà fún yín: gẹ́gẹ́ bí Baba ti rán mi, bẹ́ẹ̀ ni èmi sì rán yín."
1.218609
ku lunaku olw'obulokozi ndikuyamba.
àti ní ọjọ́ ìgbàlà, èmi yóò ràn ọ́ lọ́wọ́;
1.218392
Bwe baawulira, ne beewuunya, ne bamuleka, ne bagenda.
Nígbà tí wọ́n gbọ́ báyìí, ẹnu yà wọ́n, wọ́n bá fi í sílẹ̀, wọ́n sì bá tiwọn lọ.
1.218231
Mukama n'ayogera nti Laba, abo lye ggwanga limu, era bonna balina olulimi lumu; era kino kye batanula okukola: ne kaakano tewali ekigenda okubalema, kye baagala okukola.
OLUWA wí pé, "Ọ̀kan ni gbogbo àwọn eniyan wọnyi, èdè kan ṣoṣo ni wọ́n sì ń sọ, wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ àwọn ohun tí wọn yóo ṣe ni, kò sì ní sí ohun kan tí wọn bá dáwọ́lé láti ṣe tí yóo dẹtì fún wọn.
1.21792
Nze mbatiza na mazzi naye ye ajja kubatiza na mwoyo mutukuvu.'
8Èmi ń fi omi ṣe ìtẹ̀bọmi yín, ṣùgbọ́n Òun yóò fi Ẹ̀mí Mímọ́ ṣe ìtẹ̀bọmi yín."
1.217725
era leka abaavu n'abeetaaga batenderezenga erinnya lyo ennaku zonna.
jẹ́ kí àwọn aláìní àti tálákà yin orúkọ rẹ.
1.217203
"Emirembe gibe mu ggulu, n'ekitiibwa kibeere waggulu ennyo!"
"Àlàáfíà ní ọ̀run, àti ògo ni òkè ọ̀run!"
1.217173
Mukama atusudde, atugabudde mu mukono gwa Midiyaani.
' Ṣugbọn nisinsinyii OLUWA ti kọ̀ wá sílẹ̀, ó sì ti fi wá lé àwọn ará Midiani lọ́wọ́.
1.216541
" 'Abantu bano banzisaamu ekitiibwa kya ku mimwa,
" 'Àwọn ènìyàn wọ̀nyí fi ẹnu wọn bu ọlá fún mi
1.216528
Ku ekyo kWe tulitegeerera nti: Amazima tuli baago, mu maaso g'Oli omutima gulitutereera.
Ọ̀nà tí a óo fi mọ̀ pé a jẹ́ ẹni òtítọ́ nìyí; níwájú Ọlọrun pàápàá ọkàn wa yóo balẹ̀.
1.216511
mukama wange kabaka, bonna si baddu bamukama wange?
Ṣugbọn, oluwa mi ọba, ṣe gbogbo wọn ki nṣe iranṣẹ rẹ?
1.216177
14 Ggwe Katonda akola eby'amagero;
14Ìwọ ni Ọlọ́run tó ń ṣe ìyanu;
1.216156
Nagira ati, "Omwoyo w'amazima ku ariija aryabeebembera omu mazima goona."
Ṣugbọn nígbà tí Ẹ̀mí òtítọ́ tí mo wí bá dé, yóo tọ yín sí ọ̀nà òtítọ́ gbogbo.
1.215907
Naye yogera bwogezi kigambo, omuddu wange awone.
Ṣugbọn sọ ọrọ naa, iranṣẹ mi yio si larada.
1.215851
5 Akabatebia ng'a Omwana-o-mwanyabanto nere omonene bw'esabato.
Jesu bá sọ fún wọn pé, "Ọmọ-Eniyan ni Oluwa Ọjọ́ Ìsinmi."
1.215708
abaakola nange endagaano nga bawaayo ssaddaaka."
àwọn tí wọn fi ẹbọ dá májẹ̀mú fún mi."
1.215624
10 Balina omukisa abayigganyizibwa olw'obutuukirivu,
10Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí eniyan ń ṣe inúnibíni sí nítorí òdodo,
End of preview. Expand in Data Studio

Ganda-Yoruba_Sentence-Pairs Dataset

This dataset contains sentence pairs for African languages along with similarity scores. It can be used for machine translation, sentence alignment, or other natural language processing tasks.

This dataset is based on the NLLBv1 dataset, published on OPUS under an open-source initiative led by META. You can find more information here: OPUS - NLLB-v1

Metadata

  • File Name: Ganda-Yoruba_Sentence-Pairs
  • Number of Rows: 147769
  • Number of Columns: 3
  • Columns: score, Ganda, Yoruba

Dataset Description

The dataset contains sentence pairs in African languages with an associated similarity score. Each row consists of three columns:

  1. score: The similarity score between the two sentences (range from 0 to 1).
  2. Ganda: The first sentence in the pair (language 1).
  3. Yoruba: The second sentence in the pair (language 2).

This dataset is intended for use in training and evaluating machine learning models for tasks like translation, sentence similarity, and cross-lingual transfer learning.

References

Below are papers related to how the data was collected and used in various multilingual and cross-lingual applications:

[1] Holger Schwenk and Matthijs Douze, Learning Joint Multilingual Sentence Representations with Neural Machine Translation, ACL workshop on Representation Learning for NLP, 2017

[2] Holger Schwenk and Xian Li, A Corpus for Multilingual Document Classification in Eight Languages, LREC, pages 3548-3551, 2018.

[3] Holger Schwenk, Filtering and Mining Parallel Data in a Joint Multilingual Space ACL, July 2018

[4] Alexis Conneau, Guillaume Lample, Ruty Rinott, Adina Williams, Samuel R. Bowman, Holger Schwenk and Veselin Stoyanov, XNLI: Cross-lingual Sentence Understanding through Inference, EMNLP, 2018.

[5] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Margin-based Parallel Corpus Mining with Multilingual Sentence Embeddings arXiv, Nov 3 2018.

[6] Mikel Artetxe and Holger Schwenk, Massively Multilingual Sentence Embeddings for Zero-Shot Cross-Lingual Transfer and Beyond arXiv, Dec 26 2018.

[7] Holger Schwenk, Vishrav Chaudhary, Shuo Sun, Hongyu Gong and Paco Guzman, WikiMatrix: Mining 135M Parallel Sentences in 1620 Language Pairs from Wikipedia arXiv, July 11 2019.

[8] Holger Schwenk, Guillaume Wenzek, Sergey Edunov, Edouard Grave and Armand Joulin CCMatrix: Mining Billions of High-Quality Parallel Sentences on the WEB

[9] Paul-Ambroise Duquenne, Hongyu Gong, Holger Schwenk, Multimodal and Multilingual Embeddings for Large-Scale Speech Mining, NeurIPS 2021, pages 15748-15761.

[10] Kevin Heffernan, Onur Celebi, and Holger Schwenk, Bitext Mining Using Distilled Sentence Representations for Low-Resource Languages

Downloads last month
10

Collection including michsethowusu/ganda-yoruba_sentence-pairs